Donna Reed
Àdàkọ:Use American English Àdàkọ:Use mdy dates
Donna Reed | |
---|---|
Donna Reed in the 1950s | |
Ọjọ́ìbí | Donna Belle Mullenger Oṣù Kínní 27, 1921 Denison, Iowa, U.S. |
Aláìsí | January 14, 1986 Beverly Hills, California, U.S. | (ọmọ ọdún 64)
Resting place | Westwood Village Memorial Park Cemetery |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 1941–1986 |
Olólùfẹ́ | William J. Tuttle (m. 1943; div. 1945) Tony Owen (m. 1945; div. 1971) Grover Asmus (m. 1974) |
Àwọn ọmọ | 4 |
Donna Reed (wọ́n bí Donna Belle Mullenger; ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n oṣù kìíní , ọdún 1921 – ó sì fi ayé sílẹ̀ ní ọjọ́ kẹrìnlá, oṣù kìíní, ọdún 1986) ó jẹ́ òṣèrè Amẹ́ríkà. Ìgbà tó fi ṣe eré lọ fún bíi ogójì , pẹ̀lú àwọn ipa àti akitiyan rẹ̀ ní fíìmù tó ju ogójì lọ. Àwọn ènìyàn mọ̀ ọ́ dáadáa fún ipa rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí Mary Hatch Bailey ní eré Frank Capra tó pè ní fantasy holiday film It's a Wonderful Life (1946). Reed gba Academy Award for Best Supporting Actress fún Fred Zinnemann's war fíìmù From Here to Eternity (1953).
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Reed sí Donna Belle Mullenger ni oko lẹ́ẹ̀gbẹ́ Denison, Iowa, ó jẹ́ ọmọbìnrin fún Hazel Jane (tí ọ̀pọ̀ ènìyàn mọ̀ sí Shives) àti William Richard Mullenger.[1] òun ló dàgbà jù láàárín àwọn ọmọ márùn-ún tí àwọn òbí ẹ̀ bí, wọ́n tó dàgbà bíi mẹ́dọ́dìsì.[2] Ní ọdún 1936, nígbà tó wà ní kíláàsì tó kàn kó tó parí ìwé-ilé rẹ̀ ní Denison (Iowa) , kẹ́mísítírí tisà rẹ̀ fún un ní How to Win Friends and Influence People. Ìwé náà jẹ́ ìwé to yìí ayé ẹ̀ padà sí dáadáa . Lẹ́yìn tó kà á tán, ó gba òṣèrè àkọ́kọ́ ní eré tó ṣe ní ilé-ìwé rẹ̀, wọ́n tún dìbò fún un ní ilé-ìwé rẹ̀ fún olorì wọn àti wí pé ó wà ní àwọn mẹ́wàá àkọ́kọ́ tó ṣe tán ní ọdún 1938 ní ilé-ìwé náà. Tompkins bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣíṣe lórí Manhattan Project.[3]
Lẹ́yìn to parí ìwé ẹ̀ tàn-ná ní Denison, Reed lérò láti di olùkọ́ ṣùgbọ́n kò rówó san fún fásitìto. Nígbà náà lo padà lọ sí kalifónáì tó lọ sí ilé-ìwé Los Angeles City College ní ìmọ̀ràn ààntí rẹ̀. Nígbà tó wà ní Fásitì, ó ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ eré orí-ìtàgé, àmọ́ nígbà náà kò tì í ni lọ́kàn láti di Òṣèrè. Lẹ́yìn tí ọ̀pọ̀ àwọn pè é tó dárapọ̀ mọ́ àwọn ni ó padà darapọ̀ mọ́ screen test ní sítúdíò wọn, Reed tọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú Metro-Goldwyn-Mayer; Lẹ́yìn ìgbà náà, in pinnu láti parí ẹ̀kọ́ rẹ̀ tan náà.[4][5] Ó parí ẹ̀kọ́ Fásitì rẹ̀, lẹ́yìn náà ló tọwọ́ bọ̀wé pẹ̀lú ilé-iṣẹ́ agent.[6]
Rédíò
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
1947 | Lux Radio Theatre | Episode: It's A Wonderful Life | |
1948 | Lux Radio Theatre | Episode: You Were Meant For Me | |
1949 | Lux Radio Theatre | Episode: High Barbaree | |
1949 | Lux Radio Theatre | Episode: Deep Waters | |
1951 | Lux Radio Theatre | Episode: To Please A Lady | |
1952 | Screen Guild Theater | Episode: The Mating of Millie[7] | |
1954 | Lux Radio Theatre | Episode: The Naked Jungle | |
1955 | Lux Radio Theatre | Episode: Rawhide |
Fíìmù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Title | Role | Notes |
---|---|---|---|
1940 | Convicted Woman | Inmate | Uncredited |
1941 | The Get-Away | Maria Theresa 'Terry' O'Reilly | |
1941 | Shadow of the Thin Man | Molly | |
1941 | Babes on Broadway | Jonesy's Secretary | Uncredited |
1942 | The Bugle Sounds | Sally Hanson | |
1942 | The Courtship of Andy Hardy | Melodie Eunice Nesbit | |
1942 | Mokey | Anthea Delano | |
1942 | Calling Dr. Gillespie | Marcia Bradburn | |
1942 | Apache Trail | Rosalia Martinez | |
1942 | Eyes in the Night | Barbara Lawry | |
1942 | Personalities | Uncredited | |
1943 | The Human Comedy | Bess Macauley | |
1943 | Dr. Gillespie's Criminal Case | Marcia Bradburn | Alternative title: Crazy to Kill |
1943 | The Man from Down Under | Mary Wilson | |
1943 | Thousands Cheer | Customer in Red Skelton Skit | |
1944 | See Here, Private Hargrove | Carol Holliday | |
1944 | Gentle Annie | Mary Lingen | |
1945 | The Picture of Dorian Gray | Gladys Hallward | |
1945 | They Were Expendable | Lt. Sandy Davyss | |
1946 | Faithful in My Fashion | Jean Kendrick | |
1946 | It's a Wonderful Life | Mary Hatch Bailey | |
1947 | Green Dolphin Street | Marguerite Patourel | |
1948 | Beyond Glory | Ann Daniels | |
1949 | Chicago Deadline | Rosita Jean D'Ur | |
1951 | Saturday's Hero | Melissa | Alternative title: Idols in the Dust |
1952 | Scandal Sheet | Julie Allison | Alternative title: The Dark Page |
1952 | Rainbow 'Round My Shoulder | Herself | Uncredited |
1952 | Hangman's Knot | Molly Hull | |
1953 | Trouble Along the Way | Alice Singleton | Alternative title: Alma Mater |
1953 | Raiders of the Seven Seas | Alida | |
1953 | From Here to Eternity | Alma "Lorene" Burke | Academy Award for Best Supporting Actress |
1953 | The Caddy | Kathy Taylor | |
1953 | Gun Fury | Jennifer Ballard | |
1954 | They Rode West | Laurie MacKaye | |
1954 | Three Hours to Kill | Laurie Mastin | |
1954 | The Last Time I Saw Paris | Marion Ellswirth / Matine | |
1955 | The Far Horizons | Sacajawea | Alternative title: The Untamed West |
1956 | The Benny Goodman Story | Alice Hammond | |
1956 | Ransom! | Edith Stannard | Alternative title: Fearful Decision |
1956 | Backlash | Karyl Orton | |
1956 | Beyond Mombasa | Ann Wilson | |
1958 | The Whole Truth | Carol Poulton | |
1960 | Pepe | Herself (cameo) | |
1979 | The Best Place to Be | Sheila Callahan | TV movie |
1983 | Deadly Lessons | Miss Wade | TV movie |
Àwọn Àwọ́ọ̀dù àti àwọn ibi tó wọn tí yànnọ́ fún Àwọ́ọ̀dù
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Award | Category | Title | Result |
---|---|---|---|---|
1953 | Academy Awards | Best Supporting Actress | From Here to Eternity | Gbàá |
1964 | Bravo Otto | Best Female TV Star | The Donna Reed Show| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||||
1964 | Golden Apple Awards | Most Cooperative Actress | Gbàá | |
1963 | Golden Globe Awards | Best TV Star – Female | The Donna Reed Show | Gbàá |
2006 | Online Film & Television Association | Television Hall of Fame: Acting | Gbàá | |
1959 | Primetime Emmy Awards | Best Actress in a Leading Role (Continuing Character) in a Comedy Series| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | ||
1960 | Outstanding Performance by an Actress in a Series (Lead or Support)| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |||
1961 | Outstanding Performance by an Actress in a Series (Lead)| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |||
1962 | Outstanding Continued Performance by an Actress in a Series (Lead)| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |||
2004 | TV Land Awards | The Most Irreplaceable Replacement | Dallas| style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé | |
style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs namedfilm-ref
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs nameddrs
- ↑ "75-year history of Broadway Elementary building celebrated". Denison Bulletin-Review. March 20, 2012. Archived from the original on 2019-12-03. Retrieved April 9, 2017. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Royce 1990, p. 2.
- ↑ "Donna Reed Says Success and Beauty Depend on Happiness Lane, Lydia". Los Angeles Times: p. C9. Aug 23, 1953.
- ↑ Bawden, James; Miller, Ron (2019). Conversations with Legendary Television Stars. Lexington, Kentucky: The University Press of Kentucky. p. 275. ISBN 978-0-8131-7765-6. https://books.google.com/books?id=zS2eDwAAQBAJ&pg=PT275.
- ↑ Kirby, Walter (April 13, 1952). "Better Radio Programs for the Week". The Decatur Daily Review. p. 48. https://www.newspapers.com/clip/2394805/decatur_daily_review_april_13_1952/.